2 Kíróníkà 35:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jeremáyà+ sun rárà fún Jòsáyà, gbogbo akọrin lọ́kùnrin àti lóbìnrin+ sì ń sọ nípa Jòsáyà nínú orin arò* wọn títí di òní yìí; wọ́n pinnu pé kí wọ́n máa kọ àwọn orin náà ní Ísírẹ́lì, wọ́n sì wà lákọsílẹ̀ nínú àwọn orin arò.
25 Jeremáyà+ sun rárà fún Jòsáyà, gbogbo akọrin lọ́kùnrin àti lóbìnrin+ sì ń sọ nípa Jòsáyà nínú orin arò* wọn títí di òní yìí; wọ́n pinnu pé kí wọ́n máa kọ àwọn orin náà ní Ísírẹ́lì, wọ́n sì wà lákọsílẹ̀ nínú àwọn orin arò.