2 Àwọn Ọba 24:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹni ọdún mọ́kànlélógún (21) ni Sedekáyà nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlá (11) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hámútálì+ ọmọ Jeremáyà láti Líbínà. 19 Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà, gbogbo ohun tí Jèhóákímù ṣe ni òun náà ṣe.+
18 Ẹni ọdún mọ́kànlélógún (21) ni Sedekáyà nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlá (11) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Hámútálì+ ọmọ Jeremáyà láti Líbínà. 19 Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà, gbogbo ohun tí Jèhóákímù ṣe ni òun náà ṣe.+