1 Sámúẹ́lì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ọmọkùnrin Élì jẹ́ èèyàn burúkú;+ wọn ò ka Jèhófà sí. Ìdárò 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wòlíì rẹ̀ àti àṣìṣe àwọn àlùfáà rẹ̀,+Tí wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ àwọn olódodo sílẹ̀ láàárín rẹ̀.+
13 Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wòlíì rẹ̀ àti àṣìṣe àwọn àlùfáà rẹ̀,+Tí wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ àwọn olódodo sílẹ̀ láàárín rẹ̀.+