Léfítíkù 26:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Màá fòpin sí ìgbéraga yín, màá mú kí ojú ọ̀run yín dà bí irin+ àti ilẹ̀ yín bíi bàbà. Sefanáyà 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní ọjọ́ yẹn, ojú ò ní tì ọ́Nítorí gbogbo ohun tí o ṣe láti fi ṣọ̀tẹ̀ sí mi,+Torí nígbà náà, màá mú àwọn agbéraga tó ń fọ́nnu kúrò láàárín rẹ;O ò sì ní gbéra ga mọ́ ní òkè mímọ́ mi.+
11 Ní ọjọ́ yẹn, ojú ò ní tì ọ́Nítorí gbogbo ohun tí o ṣe láti fi ṣọ̀tẹ̀ sí mi,+Torí nígbà náà, màá mú àwọn agbéraga tó ń fọ́nnu kúrò láàárín rẹ;O ò sì ní gbéra ga mọ́ ní òkè mímọ́ mi.+