ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 29:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Kí ẹnu yà yín, kí ẹ sì ṣe kàyéfì;+

      Ẹ fọ́ ara yín lójú, kí ẹ sì fọ́jú.+

      Wọ́n ti yó, àmọ́ kì í ṣe wáìnì ni wọ́n mu yó;

      Wọ́n ń ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́, àmọ́ kì í ṣe ọtí ló ń mú kí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀.

  • Àìsáyà 51:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Jí! Jí! Dìde, ìwọ Jerúsálẹ́mù,+

      Ìwọ tí o ti mu ife ìbínú Jèhófà láti ọwọ́ rẹ̀.

      O ti mu látinú aago náà;

      O ti mu ife tó ń múni ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́ gbẹ.+

  • Jeremáyà 25:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 “Kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí: “Ẹ mu, kí ẹ sì yó, ẹ bì, kí ẹ sì ṣubú, tí ẹ kò fi ní lè dìde+ nítorí idà tí màá rán sáàárín yín.”’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́