Àìsáyà 59:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìdí nìyẹn tí ìdájọ́ òdodo fi jìnnà sí wa,Tí òdodo kò sì lé wa bá. À ń retí ìmọ́lẹ̀ ṣáá, àmọ́ wò ó! òkùnkùn ló ṣú;À ń retí ìmọ́lẹ̀ tó tàn yòò, àmọ́ a ò yéé rìn nínú ìṣúdùdù.+
9 Ìdí nìyẹn tí ìdájọ́ òdodo fi jìnnà sí wa,Tí òdodo kò sì lé wa bá. À ń retí ìmọ́lẹ̀ ṣáá, àmọ́ wò ó! òkùnkùn ló ṣú;À ń retí ìmọ́lẹ̀ tó tàn yòò, àmọ́ a ò yéé rìn nínú ìṣúdùdù.+