Dáníẹ́lì 9:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Jèhófà, jọ̀ọ́ tẹ́tí gbọ́. Jèhófà, jọ̀ọ́ dárí jì.+ Jèhófà, jọ̀ọ́ fiyè sí wa, kí o sì gbé ìgbésẹ̀! Má ṣe jẹ́ kó pẹ́, torí tìẹ, Ọlọ́run mi, torí orúkọ rẹ la fi pe ìlú rẹ àti àwọn èèyàn rẹ.”+
19 Jèhófà, jọ̀ọ́ tẹ́tí gbọ́. Jèhófà, jọ̀ọ́ dárí jì.+ Jèhófà, jọ̀ọ́ fiyè sí wa, kí o sì gbé ìgbésẹ̀! Má ṣe jẹ́ kó pẹ́, torí tìẹ, Ọlọ́run mi, torí orúkọ rẹ la fi pe ìlú rẹ àti àwọn èèyàn rẹ.”+