-
Jeremáyà 2:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Báwo lo ṣe máa sọ pé, ‘Mi ò sọ ara mi di ẹlẹ́gbin.
Mi ò sì tẹ̀ lé Báálì’?
Wo ọ̀nà rẹ ní àfonífojì.
Wo ohun tí o ti ṣe.
O dà bí abo ọmọ ràkúnmí tó yára,
Tó ń sá lọ sá bọ̀ ní ọ̀nà rẹ̀ láìsí ohun tó ń lé e,
-