ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 5:12, 13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 “Wọ́n ti kọ Jèhófà, wọ́n sì ń sọ pé,

      ‘Kò ní ṣe nǹkan kan.*+

      Àjálù kankan kò ní bá wa;

      A kò ní rí idà tàbí ìyàn.’+

      13 Àwọn wòlíì jẹ́ àgbá òfìfo,

      Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run kò sì sí lẹ́nu wọn.

      Kí ó rí bẹ́ẹ̀ fún wọn!”

  • Jeremáyà 23:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ sí àwọn wòlíì náà nìyí:

      “Wò ó, màá mú kí wọ́n jẹ iwọ*

      Màá sì fún wọn ní omi tó ní májèlé mu.+

      Nítorí láti ọ̀dọ̀ àwọn wòlíì Jerúsálẹ́mù ni ìpẹ̀yìndà ti tàn káàkiri ilẹ̀ náà.”

  • Ìsíkíẹ́lì 12:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Torí kò ní sí ìran èké tàbí ìwoṣẹ́ ẹ̀tàn mọ́ nínú ilé Ísírẹ́lì.+

  • Ìsíkíẹ́lì 13:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àwọn wòlíì tó ń rí ìran èké àti àwọn tó ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ irọ́ máa jìyà lọ́wọ́ mi.+ Wọn ò ní sí lára àwọn èèyàn tí mo fọkàn tán; orúkọ wọn ò ní sí nínú àkọsílẹ̀ orúkọ ilé Ísírẹ́lì; wọn ò ní pa dà sórí ilẹ̀ Ísírẹ́lì; ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́