-
Nehemáyà 13:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Mo pàṣẹ pé kí wọ́n ti àwọn ẹnubodè Jerúsálẹ́mù pa kí ilẹ̀ tó ṣú, ìyẹn kí Sábáàtì tó bẹ̀rẹ̀. Mo tún sọ pé wọn ò gbọ́dọ̀ ṣí wọn títí di ẹ̀yìn Sábáàtì, mo fi lára àwọn ìránṣẹ́ mi sí àwọn ẹnubodè náà kí wọ́n má bàa kó ẹrù kankan wọlé ní ọjọ́ Sábáàtì.
-