ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 48:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Torí mo mọ bí o ṣe lágídí tó,

      Pé irin ni iṣan ọrùn rẹ àti pé bàbà ni iwájú orí rẹ,+

  • Ìsíkíẹ́lì 20:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 “‘“Àmọ́, ilé Ísírẹ́lì ṣọ̀tẹ̀ sí mi ní aginjù.+ Wọn ò tẹ̀ lé àwọn àṣẹ mi, wọ́n sì kọ àwọn ìdájọ́ mi, èyí tó lè mú kí ẹni tó bá ń pa wọ́n mọ́ wà láàyè. Wọ́n sọ àwọn sábáàtì mi di aláìmọ́ pátápátá. Torí náà, mo pinnu pé màá bínú sí wọn nínú aginjù kí n lè pa wọ́n run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́