-
Jeremáyà 2:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ìwà búburú rẹ ni yóò tọ́ ọ sọ́nà,
Ìwà àìṣòótọ́ rẹ ni yóò sì bá ọ wí.
-
-
Jeremáyà 3:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 A gbọ́ ìró kan lórí àwọn òkè kéékèèké,
Ẹkún àti àrọwà àwọn èèyàn Ísírẹ́lì,
Nítorí wọ́n lọ́ ọ̀nà wọn po;
Wọ́n ti gbàgbé Jèhófà Ọlọ́run wọn.+
-