Jeremáyà 10:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kálukú ń hùwà láìronú, wọn ò sì ní ìmọ̀. Ojú á ti gbogbo oníṣẹ́ irin nítorí ère tí wọ́n ṣe;+Nítorí ère onírin* rẹ̀ jẹ́ èké,Kò sì sí ẹ̀mí* kankan nínú wọn.+ 15 Ẹ̀tàn* ni wọ́n, iṣẹ́ yẹ̀yẹ́ sì ni wọ́n.+ Nígbà tí ọjọ́ ìbẹ̀wò wọn bá dé, wọ́n á ṣègbé.
14 Kálukú ń hùwà láìronú, wọn ò sì ní ìmọ̀. Ojú á ti gbogbo oníṣẹ́ irin nítorí ère tí wọ́n ṣe;+Nítorí ère onírin* rẹ̀ jẹ́ èké,Kò sì sí ẹ̀mí* kankan nínú wọn.+ 15 Ẹ̀tàn* ni wọ́n, iṣẹ́ yẹ̀yẹ́ sì ni wọ́n.+ Nígbà tí ọjọ́ ìbẹ̀wò wọn bá dé, wọ́n á ṣègbé.