ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 22:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Màá mú àjálù bá ibí yìí àti àwọn tó ń gbé ibẹ̀, gbogbo ohun tó wà nínú ìwé tí ọba Júdà kà ni màá ṣe.+ 17 Nítorí pé wọ́n ti fi mí sílẹ̀, wọ́n sì ń mú ẹbọ rú èéfín sí àwọn ọlọ́run míì+ láti fi gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ wọn mú mi bínú,+ ìbínú mi máa bẹ̀rẹ̀ sí í jó bí iná lórí ibí yìí, kò sì ní ṣeé pa.’”+

  • Àìsáyà 65:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àmọ́ ẹ wà lára àwọn tó ń fi Jèhófà sílẹ̀,+

      Àwọn tó ń gbàgbé òkè mímọ́ mi,+

      Àwọn tó ń tẹ́ tábìlì fún ọlọ́run Oríire

      Àti àwọn tó ń bu àdàlù wáìnì kún inú ife fún ọlọ́run Àyànmọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́