-
Ìsíkíẹ́lì 3:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ẹ̀mí náà gbé mi, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í mú mi lọ. Inú mi bà jẹ́, inú sì ń bí mi bí mo ṣe ń lọ, ọwọ́ Jèhófà wà lára mi lọ́nà tó lágbára.
-
-
Míkà 3:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ní tèmi, ẹ̀mí Jèhófà ti fún mi ní agbára,
Ó ti jẹ́ kí n lè ṣe ìdájọ́ òdodo, ó sì ti fún mi lókun,
Kí n lè sọ fún Jékọ́bù nípa ọ̀tẹ̀ tó dì, kí n sì sọ ẹ̀ṣẹ̀ Ísírẹ́lì fún un.
-