Diutarónómì 32:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè. Àìsáyà 1:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ọkùnrin alágbára máa di èétú okùn,*Iṣẹ́ rẹ̀ sì máa ta pàrà;Iná máa jó àwọn méjèèjì pa pọ̀,Kò sì ní sẹ́ni tó máa pa iná náà.” Jeremáyà 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Wò ó! Ìbínú mi àti ìrunú mi yóò dà sórí ibí yìí,+ sórí èèyàn àti ẹranko, sórí igi oko àti èso ilẹ̀. Ìbínú mi yóò máa jó bí iná tí kò ṣeé pa.’+
22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè.
31 Ọkùnrin alágbára máa di èétú okùn,*Iṣẹ́ rẹ̀ sì máa ta pàrà;Iná máa jó àwọn méjèèjì pa pọ̀,Kò sì ní sẹ́ni tó máa pa iná náà.”
20 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Wò ó! Ìbínú mi àti ìrunú mi yóò dà sórí ibí yìí,+ sórí èèyàn àti ẹranko, sórí igi oko àti èso ilẹ̀. Ìbínú mi yóò máa jó bí iná tí kò ṣeé pa.’+