Diutarónómì 32:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 “Gun òkè Ábárímù+ yìí lọ, Òkè Nébò,+ tó wà ní ilẹ̀ Móábù, tó dojú kọ Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénáánì, tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kó di tiwọn.+
49 “Gun òkè Ábárímù+ yìí lọ, Òkè Nébò,+ tó wà ní ilẹ̀ Móábù, tó dojú kọ Jẹ́ríkò, kí o sì wo ilẹ̀ Kénáánì, tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kó di tiwọn.+