2 Àwọn Ọba 24:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọba Íjíbítì kò tún jáde kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀ mọ́, torí pé ọba Bábílónì ti gba gbogbo ohun tí ọba Íjíbítì ní,+ ìyẹn láti Àfonífojì Íjíbítì+ títí dé odò Yúfírétì.+
7 Ọba Íjíbítì kò tún jáde kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀ mọ́, torí pé ọba Bábílónì ti gba gbogbo ohun tí ọba Íjíbítì ní,+ ìyẹn láti Àfonífojì Íjíbítì+ títí dé odò Yúfírétì.+