-
Jeremáyà 2:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Áà ìran yìí, ẹ kíyè sí ọ̀rọ̀ Jèhófà.
Ṣé mo ti dà bí aginjù lójú Ísírẹ́lì ni
Tàbí ilẹ̀ òkùnkùn biribiri?
Kí ló dé tí àwọn èèyàn mi yìí fi sọ pé, ‘À ń rìn kiri fàlàlà.
A kò ní wá sọ́dọ̀ rẹ mọ́’?+
-