2 Àwọn Ọba 23:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Yàtọ̀ síyẹn, Fáráò Nẹ́kò fi Élíákímù ọmọ Jòsáyà jọba ní ipò Jòsáyà bàbá rẹ̀, ó sì yí orúkọ rẹ̀ pa dà sí Jèhóákímù; àmọ́ ó mú Jèhóáhásì wá sí Íjíbítì,+ ibẹ̀ ló sì kú sí nígbẹ̀yìn.+
34 Yàtọ̀ síyẹn, Fáráò Nẹ́kò fi Élíákímù ọmọ Jòsáyà jọba ní ipò Jòsáyà bàbá rẹ̀, ó sì yí orúkọ rẹ̀ pa dà sí Jèhóákímù; àmọ́ ó mú Jèhóáhásì wá sí Íjíbítì,+ ibẹ̀ ló sì kú sí nígbẹ̀yìn.+