Diutarónómì 32:37, 38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Ó máa wá sọ pé, ‘Àwọn ọlọ́run+ wọn dà,Àpáta tí wọ́n sá di, 38 Tó máa ń jẹ ọ̀rá àwọn ẹbọ wọn,*Tó ń mu wáìnì ọrẹ ohun mímu+ wọn? Jẹ́ kí wọ́n dìde wá ràn yín lọ́wọ́.Kí wọ́n di ibi ààbò fún yín.
37 Ó máa wá sọ pé, ‘Àwọn ọlọ́run+ wọn dà,Àpáta tí wọ́n sá di, 38 Tó máa ń jẹ ọ̀rá àwọn ẹbọ wọn,*Tó ń mu wáìnì ọrẹ ohun mímu+ wọn? Jẹ́ kí wọ́n dìde wá ràn yín lọ́wọ́.Kí wọ́n di ibi ààbò fún yín.