Ìsíkíẹ́lì 16:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 “‘Samáríà ni ẹ̀gbọ́n rẹ obìnrin,+ tí òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin* ń gbé ní àríwá rẹ.*+ Sódómù+ sì ni àbúrò rẹ obìnrin, tí òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin ń gbé ní gúúsù rẹ.*+
46 “‘Samáríà ni ẹ̀gbọ́n rẹ obìnrin,+ tí òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin* ń gbé ní àríwá rẹ.*+ Sódómù+ sì ni àbúrò rẹ obìnrin, tí òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin ń gbé ní gúúsù rẹ.*+