-
Ìsíkíẹ́lì 13:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ṣebí ìran èké lẹ rí, àsọtẹ́lẹ̀ irọ́ lẹ sì sọ nígbà tí ẹ sọ pé, ‘Ọ̀rọ̀ Jèhófà ni pé,’ tó sì jẹ́ pé mi ò sọ nǹkan kan?”’