ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 50:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Nítorí wò ó, màá gbé àwọn orílẹ̀-èdè ńlá dìde láti ilẹ̀ àríwá

      Màá sì mú kí wọ́n gbéjà ko Bábílónì.+

      Wọ́n á tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti gbógun tì í;

      Ibẹ̀ ni wọ́n á ti gbà á.

      Ọfà wọn dà bíi ti jagunjagun

      Tó ń múni ṣòfò ọmọ;+

      Wọn kì í pa dà wá lọ́wọ́ òfo.

  • Jeremáyà 51:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 “Ẹ gbé àmì kan sókè* ní ilẹ̀ náà.+

      Ẹ fun ìwo láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.

      Ẹ yan àwọn orílẹ̀-èdè* lé e lórí.

      Ẹ pe àwọn ìjọba Árárátì,+ Mínì àti Áṣíkénásì+ láti wá gbéjà kò ó.

      Ẹ yan agbanisíṣẹ́ ogun láti wá gbéjà kò ó.

      Ẹ jẹ́ kí àwọn ẹṣin gòkè wá bí eéṣú onírun gàn-ùn gàn-ùn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́