-
Jeremáyà 49:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ẹ sá pa dà!
Ẹ lọ máa gbé ní àwọn ibi tó jin kòtò, ẹ̀yin tó ń gbé ní Dédánì!+
Nítorí màá mú àjálù bá Ísọ̀
Nígbà tí àkókò tí màá yí ojú mi sí i bá tó.
-