Ẹ́kísódù 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Mósè wá sọ fún Jèhófà pé: “Má bínú, Jèhófà, mi ò lè sọ̀rọ̀ dáadáa ṣáájú àkókò yìí àti lẹ́yìn tí o bá ìránṣẹ́ rẹ sọ̀rọ̀, torí ọ̀rọ̀ mi ò já geere,* ahọ́n mi sì wúwo.”+
10 Mósè wá sọ fún Jèhófà pé: “Má bínú, Jèhófà, mi ò lè sọ̀rọ̀ dáadáa ṣáájú àkókò yìí àti lẹ́yìn tí o bá ìránṣẹ́ rẹ sọ̀rọ̀, torí ọ̀rọ̀ mi ò já geere,* ahọ́n mi sì wúwo.”+