Míkà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún Míkà*+ ará Móréṣétì, nínú ìran tó rí nípa Samáríà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ tí wọ́n jẹ́ ọba Júdà:+
1 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún Míkà*+ ará Móréṣétì, nínú ìran tó rí nípa Samáríà àti Jerúsálẹ́mù láyé ìgbà Jótámù,+ Áhásì+ àti Hẹsikáyà,+ tí wọ́n jẹ́ ọba Júdà:+