ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 11:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Kò sí ìlú kankan tó bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rẹ́ àfi àwọn Hífì tó ń gbé ní Gíbíónì.+ Gbogbo àwọn yòókù ni wọ́n bá jà tí wọ́n sì ṣẹ́gun wọn.+

  • 2 Sámúẹ́lì 21:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Torí náà, ọba pe àwọn ará Gíbíónì,+ ó sì bá wọn sọ̀rọ̀. (Àwọn ará Gíbíónì kì í ṣe ara àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n jẹ́ àwọn Ámórì+ tó ṣẹ́ kù, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ti búra pé àwọn máa dá wọn sí,+ àmọ́ Sọ́ọ̀lù wá ọ̀nà títí ó fi pa wọ́n nítorí ìtara tó ní fún àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti Júdà lọ́nà òdì.)

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́