Jeremáyà 28:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “‘Màá sì mú Jekonáyà+ ọmọ Jèhóákímù,+ ọba Júdà àti gbogbo ará Júdà tó wà ní ìgbèkùn ní Bábílónì+ pa dà wá sí ibí yìí,’ ni Jèhófà wí, ‘nítorí màá ṣẹ́ àjàgà ọba Bábílónì.’”
4 “‘Màá sì mú Jekonáyà+ ọmọ Jèhóákímù,+ ọba Júdà àti gbogbo ará Júdà tó wà ní ìgbèkùn ní Bábílónì+ pa dà wá sí ibí yìí,’ ni Jèhófà wí, ‘nítorí màá ṣẹ́ àjàgà ọba Bábílónì.’”