-
Jeremáyà 6:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ǹjẹ́ ojú tì wọ́n nítorí àwọn ohun ìríra tí wọ́n ṣe?
Ojú kì í tì wọ́n!
Àní wọn ò tiẹ̀ lójútì rárá!+
Torí náà, wọ́n á ṣubú láàárín àwọn tó ti ṣubú.
Nígbà tí mo bá fìyà jẹ wọ́n, wọ́n á kọsẹ̀,” ni Jèhófà wí.
-