Jeremáyà 31:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 ‘Ìrètí wà fún ọ ní ọjọ́ ọ̀la,’+ ni Jèhófà wí. ‘Àwọn ọmọ rẹ á sì pa dà sí ilẹ̀ wọn.’”+