Jeremáyà 6:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè ayé! Màá mú àjálù bá àwọn èèyàn yìí+Wọ́n á jèrè èrò ibi wọn,Torí wọn kò fiyè sí ọ̀rọ̀ miWọ́n sì kọ òfin* mi.”
19 Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè ayé! Màá mú àjálù bá àwọn èèyàn yìí+Wọ́n á jèrè èrò ibi wọn,Torí wọn kò fiyè sí ọ̀rọ̀ miWọ́n sì kọ òfin* mi.”