Jeremáyà 23:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo ti rí àwọn ohun tó burú nínú àwọn wòlíì Jerúsálẹ́mù. Wọ́n ń ṣe àgbèrè,+ wọ́n sì ń rìn nínú èké;+Wọ́n ń ti àwọn aṣebi lẹ́yìn,*Wọn ò sì jáwọ́ nínú ìwà burúkú wọn. Lójú mi, gbogbo wọn dà bíi Sódómù,+Àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ sì dà bíi Gòmórà.”+
14 Mo ti rí àwọn ohun tó burú nínú àwọn wòlíì Jerúsálẹ́mù. Wọ́n ń ṣe àgbèrè,+ wọ́n sì ń rìn nínú èké;+Wọ́n ń ti àwọn aṣebi lẹ́yìn,*Wọn ò sì jáwọ́ nínú ìwà burúkú wọn. Lójú mi, gbogbo wọn dà bíi Sódómù,+Àwọn tó ń gbé inú rẹ̀ sì dà bíi Gòmórà.”+