-
Jeremáyà 5:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ìdí nìyẹn tí kìnnìún inú igbó fi bẹ́ mọ́ wọn,
Tí ìkookò inú aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ń pa wọ́n jẹ,
Tí àmọ̀tẹ́kùn sì lúgọ ní àwọn ìlú wọn.
Gbogbo ẹni tó ń jáde láti inú wọn ló máa fà ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ.
Torí pé ìṣìnà wọn pọ̀;
Ìwà àìṣòótọ́ wọn sì pọ̀.+
-