ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 17:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Jèhófà lo gbogbo wòlíì rẹ̀ àti gbogbo aríran+ rẹ̀ láti máa kìlọ̀ fún Ísírẹ́lì àti Júdà pé: “Ẹ kúrò nínú àwọn ọ̀nà búburú yín!+ Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìlànà mi mọ́, bó ṣe wà nínú gbogbo òfin tí mo pa láṣẹ fún àwọn baba ńlá yín, tí mo sì fi rán àwọn ìránṣẹ́ mi wòlíì sí yín.”

  • 2 Kíróníkà 30:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Lẹ́yìn náà, àwọn asáréjíṣẹ́* lọ káàkiri gbogbo Ísírẹ́lì àti Júdà pẹ̀lú àwọn lẹ́tà látọ̀dọ̀ ọba àti àwọn ìjòyè rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ọba ti pa á láṣẹ, ó ní: “Ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run Ábúráhámù, Ísákì àti Ísírẹ́lì, kí ó lè pa dà sọ́dọ̀ àwọn tó ṣẹ́ kù tí wọ́n sá kúrò lọ́wọ́ àwọn ọba Ásíríà.+

  • Hósíà 14:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “Pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ, ìwọ Ísírẹ́lì,+

      Torí àṣìṣe rẹ ti mú kí o kọsẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́