-
Sekaráyà 2:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Torí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, lẹ́yìn tí a ti yìn ín lógo, ó rán mi sí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń kó ẹrù yín,+ pé; ‘Ẹni tó bá fọwọ́ kàn yín ń fọwọ́ kan ẹyinjú* mi.+ 9 Wọ́n á rí ìbínú mi, àwọn ìránṣẹ́ wọn yóò sì kó ẹrù wọn.’+ Ó sì dájú pé ẹ máa mọ̀ pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló rán mi.
-