Hósíà 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Màá gbìn ín bí irúgbìn fún ara mi sórí ilẹ̀,+Màá sì ṣàánú rẹ̀, bí wọn ò tiẹ̀ ṣàánú rẹ̀;*Màá sọ fún àwọn tí kì í ṣe èèyàn mi pé:* “Èèyàn mi ni yín”,+Àwọn náà á sì sọ pé: “Ìwọ ni Ọlọ́run wa.”’”+
23 Màá gbìn ín bí irúgbìn fún ara mi sórí ilẹ̀,+Màá sì ṣàánú rẹ̀, bí wọn ò tiẹ̀ ṣàánú rẹ̀;*Màá sọ fún àwọn tí kì í ṣe èèyàn mi pé:* “Èèyàn mi ni yín”,+Àwọn náà á sì sọ pé: “Ìwọ ni Ọlọ́run wa.”’”+