-
Jeremáyà 31:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 “Ní àkókò yẹn,” ni Jèhófà wí, “màá di Ọlọ́run gbogbo ìdílé Ísírẹ́lì, wọ́n á sì di èèyàn mi.”+
-
-
Ìsíkíẹ́lì 11:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 kí wọ́n lè máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́, kí wọ́n máa tẹ̀ lé ìdájọ́ mi, kí wọ́n sì máa rìn nínú rẹ̀. Wọ́n á wá di èèyàn mi, èmi yóò sì di Ọlọ́run wọn.”’
-
-
Ìsíkíẹ́lì 36:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ẹ ó wá máa gbé ní ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá yín, ẹ ó di èèyàn mi, màá sì di Ọlọ́run yín.’+
-