Jeremáyà 4:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nítorí èyí, ilẹ̀ náà máa ṣọ̀fọ̀,+Àwọn ọ̀run á sì ṣókùnkùn.+ Torí pé mo ti sọ̀rọ̀, mo sì ti pinnu,Mi ò ní pèrò dà,* bẹ́ẹ̀ sì ni mi ò ní yí pa dà.+
28 Nítorí èyí, ilẹ̀ náà máa ṣọ̀fọ̀,+Àwọn ọ̀run á sì ṣókùnkùn.+ Torí pé mo ti sọ̀rọ̀, mo sì ti pinnu,Mi ò ní pèrò dà,* bẹ́ẹ̀ sì ni mi ò ní yí pa dà.+