Àìsáyà 43:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Màá sọ fún àríwá pé, ‘Dá wọn sílẹ̀!’+ Màá sì sọ fún gúúsù pé, ‘Má ṣe dá wọn dúró. Mú àwọn ọmọkùnrin mi wá láti ọ̀nà jíjìn àti àwọn ọmọbìnrin mi láti àwọn ìkángun ayé,+ Jeremáyà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Lọ, kí o sì kéde ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún àríwá pé:+ “‘“Pa dà, ìwọ Ísírẹ́lì ọ̀dàlẹ̀,” ni Jèhófà wí.’+ ‘“Mi ò ní wò ọ́ tìbínútìbínú,*+ nítorí adúróṣinṣin ni mí,” ni Jèhófà wí.’ ‘“Mi ò sì ní máa bínú títí láé.
6 Màá sọ fún àríwá pé, ‘Dá wọn sílẹ̀!’+ Màá sì sọ fún gúúsù pé, ‘Má ṣe dá wọn dúró. Mú àwọn ọmọkùnrin mi wá láti ọ̀nà jíjìn àti àwọn ọmọbìnrin mi láti àwọn ìkángun ayé,+ Jeremáyà 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Lọ, kí o sì kéde ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún àríwá pé:+ “‘“Pa dà, ìwọ Ísírẹ́lì ọ̀dàlẹ̀,” ni Jèhófà wí.’+ ‘“Mi ò ní wò ọ́ tìbínútìbínú,*+ nítorí adúróṣinṣin ni mí,” ni Jèhófà wí.’ ‘“Mi ò sì ní máa bínú títí láé.
12 Lọ, kí o sì kéde ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún àríwá pé:+ “‘“Pa dà, ìwọ Ísírẹ́lì ọ̀dàlẹ̀,” ni Jèhófà wí.’+ ‘“Mi ò ní wò ọ́ tìbínútìbínú,*+ nítorí adúróṣinṣin ni mí,” ni Jèhófà wí.’ ‘“Mi ò sì ní máa bínú títí láé.