Jeremáyà 31:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n á wá pẹ̀lú ẹkún.+ Màá máa darí wọn bí wọ́n ṣe ń wá ojú rere. Màá ṣamọ̀nà wọn lọ sí ìṣàn* omi,+Lórí ọ̀nà tó tẹ́jú tí wọn ò ti ní kọsẹ̀. Nítorí èmi ni Bàbá Ísírẹ́lì, Éfúrémù sì ni àkọ́bí mi.”+ Hósíà 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Màá wo àìṣòótọ́ wọn sàn.+ Màá nífẹ̀ẹ́ wọn láti ọkàn mi wá,+Torí pé mi ò bínú sí wọn mọ́.+
9 Wọ́n á wá pẹ̀lú ẹkún.+ Màá máa darí wọn bí wọ́n ṣe ń wá ojú rere. Màá ṣamọ̀nà wọn lọ sí ìṣàn* omi,+Lórí ọ̀nà tó tẹ́jú tí wọn ò ti ní kọsẹ̀. Nítorí èmi ni Bàbá Ísírẹ́lì, Éfúrémù sì ni àkọ́bí mi.”+