Ìsíkíẹ́lì 16:59 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 “Torí ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Ní báyìí, ohun tí o ṣe sí mi ni màá fi hùwà sí ọ,+ torí o fojú kéré ìbúra tí o ṣe ní ti pé o da májẹ̀mú mi.+
59 “Torí ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Ní báyìí, ohun tí o ṣe sí mi ni màá fi hùwà sí ọ,+ torí o fojú kéré ìbúra tí o ṣe ní ti pé o da májẹ̀mú mi.+