Àìsáyà 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+ Hábákúkù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí gbogbo ayé yóò ní ìmọ̀ nípa ògo Jèhófà Bí ìgbà tí omi bo òkun.+
9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,Bí omi ṣe ń bo òkun.+