Sáàmù 122:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 A kọ́ Jerúsálẹ́mù bí ìlú,Ó so pọ̀ mọ́ra.+ 4 Àwọn ẹ̀yà ti lọ síbẹ̀,Àwọn ẹ̀yà Jáà,*Kí wọ́n lè fi ọpẹ́ fún orúkọ Jèhófà,Gẹ́gẹ́ bí ìrántí fún Ísírẹ́lì.+
3 A kọ́ Jerúsálẹ́mù bí ìlú,Ó so pọ̀ mọ́ra.+ 4 Àwọn ẹ̀yà ti lọ síbẹ̀,Àwọn ẹ̀yà Jáà,*Kí wọ́n lè fi ọpẹ́ fún orúkọ Jèhófà,Gẹ́gẹ́ bí ìrántí fún Ísírẹ́lì.+