Àìsáyà 3:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn ẹnu ọ̀nà rẹ̀ máa ṣọ̀fọ̀, wọ́n á sì kẹ́dùn,+Ó sì máa jókòó sí ilẹ̀, ó máa di ahoro.”+