ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 8:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “Kí nìdí tí a fi jókòó síbí?

      Ẹ jẹ́ ká kóra jọ, ká wọnú àwọn ìlú olódi,+ ká sì ṣègbé síbẹ̀.

      Nítorí Jèhófà Ọlọ́run wa máa pa wá run,

      Ó fún wa ní omi tó ní májèlé mu,+

      Torí pé a ti ṣẹ Jèhófà.

  • Jeremáyà 9:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Nítorí náà, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ pé, ‘Wò ó, màá mú kí àwọn èèyàn yìí jẹ iwọ,* màá sì mú kí wọ́n mu omi tó ní májèlé.+

  • Ìdárò 3:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Rántí ìyà tó ń jẹ mí àti bí mi ò ṣe rílé gbé,+ má gbàgbé pé mo jẹ iwọ* àti májèlé kíkorò.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́