6 Mò ń retí Jèhófà,+
Ju bí àwọn olùṣọ́ ṣe ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́,+
Àní, ju bí àwọn olùṣọ́ ṣe ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́.
7 Kí Ísírẹ́lì máa dúró de Jèhófà,
Nítorí ìfẹ́ Jèhófà kì í yẹ̀,+
Ó sì ní agbára ńlá tó lè fi rani pa dà.
8 Yóò ra Ísírẹ́lì pa dà nínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn.