-
Ìsíkíẹ́lì 16:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Bí mo ti wà láàyè,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘Sódómù arábìnrin rẹ àti àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin kò ṣe ohun tí ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ obìnrin ti ṣe.
-