Jóṣúà 20:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí ẹni náà sá lọ sí ọ̀kan nínú àwọn ìlú yìí,+ kó dúró sí ẹnubodè ìlú náà,+ kó sì ro ẹjọ́ rẹ̀ ní etí àwọn àgbààgbà ìlú náà. Kí wọ́n wá gbà á sínú ìlú náà, kí wọ́n fún un ní ibì kan, kó sì máa bá wọn gbé.
4 Kí ẹni náà sá lọ sí ọ̀kan nínú àwọn ìlú yìí,+ kó dúró sí ẹnubodè ìlú náà,+ kó sì ro ẹjọ́ rẹ̀ ní etí àwọn àgbààgbà ìlú náà. Kí wọ́n wá gbà á sínú ìlú náà, kí wọ́n fún un ní ibì kan, kó sì máa bá wọn gbé.