-
Ìdárò 1:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Kí gbogbo ìwà búburú wọn wá síwájú rẹ, kí o sì fìyà jẹ wọ́n,+
Bí o ṣe fìyà jẹ mí nítorí gbogbo àṣìṣe mi.
Nítorí ẹ̀dùn ọkàn mi pọ̀, ọkàn mi sì ń ṣàárẹ̀.
-